caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Baqara, ẹsẹ 45

Medina · revelation order 87 · 2:45

وَٱسْتَعِينُوا۟ بِٱلصَّبْرِ وَٱلصَّلَوٰةِ وَإِنَّهَا لَكَبِيرَةٌ إِلَّا عَلَى ٱلْخَٰشِعِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelẸ wá ìrànlọ́wọ́ (àti oore Allāhu) pẹ̀lú sùúrù[1] àti ìrun kíkí. Dájúdájú ó lágbára (láti ṣe bẹ́ẹ̀) àyàfi fún àwọn olùpáyà (Allāhu),
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70