caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Kahf, ẹsẹ 87

Mecca · revelation order 69 · 18:87

قَالَ أَمَّا مَن ظَلَمَ فَسَوْفَ نُعَذِّبُهُۥ ثُمَّ يُرَدُّ إِلَىٰ رَبِّهِۦ فَيُعَذِّبُهُۥ عَذَابًا نُّكْرًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Thul-Ƙọrnaen) sọ pé: “Ní ti ẹni tí ó bá ṣàbòsí, láìpẹ́ a máa jẹ ẹ́ níyà. Lẹ́yìn náà, wọn máa dá a padà sí ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ̀. Ó sì máa jẹ ẹ́ níyà tó burú.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70