caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Israa, ẹsẹ 94

Mecca · revelation order 50 · 17:94

وَمَا مَنَعَ ٱلنَّاسَ أَن يُؤْمِنُوٓا۟ إِذْ جَآءَهُمُ ٱلْهُدَىٰٓ إِلَّآ أَن قَالُوٓا۟ أَبَعَثَ ٱللَّهُ بَشَرًا رَّسُولًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelKò sí ohun tí ó kọ̀ fún àwọn ènìyàn láti gbàgbọ́ ní òdodo nígbà tí ìmọ̀nà dé bá wọn àfi kí wọ́n wí pé: “Ṣé Allāhu rán Òjíṣẹ́ abara níṣẹ́ ni?”
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70