caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà An-Nahl, ẹsẹ 53

Mecca · revelation order 70 · 16:53

وَمَا بِكُم مِّن نِّعْمَةٍ فَمِنَ ٱللَّهِ ثُمَّ إِذَا مَسَّكُمُ ٱلضُّرُّ فَإِلَيْهِ تَجْـَٔرُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelOhunkóhun tí ẹ ní nínú ìdẹ̀ra, láti ọ̀dọ̀ Allāhu ni. Lẹ́yìn náà, tí ọwọ́ ìnira bá tẹ̀ yín, Òun ni ẹ̀ ń ké pè (fún ìdáǹdè.)
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70