caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Yusuf, ẹsẹ 93

Mecca · revelation order 53 · 12:93

ٱذْهَبُوا۟ بِقَمِيصِى هَٰذَا فَأَلْقُوهُ عَلَىٰ وَجْهِ أَبِى يَأْتِ بَصِيرًا وَأْتُونِى بِأَهْلِكُمْ أَجْمَعِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelẸ mú ẹ̀wù mi yìí lọ, kí ẹ fi lé iwájú bàbá mi, ó máa padà di olùríran. Kí ẹ sì kó gbogbo ẹbí yín wá bá mi.”
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70