caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Yusuf, ẹsẹ 14

Mecca · revelation order 53 · 12:14

قَالُوا۟ لَئِنْ أَكَلَهُ ٱلذِّئْبُ وَنَحْنُ عُصْبَةٌ إِنَّآ إِذًا لَّخَٰسِرُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelWọ́n sọ pé: “Tí ìkokò bá fi pa á jẹ, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì ni wá, dájúdájú àwa nígbà náà ni ẹni òfò.”
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70