caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Anfaal, ẹsẹ 51

Medina · revelation order 88 · 8:51

ذَٰلِكَ بِمَا قَدَّمَتْ أَيْدِيكُمْ وَأَنَّ ٱللَّهَ لَيْسَ بِظَلَّٰمٍ لِّلْعَبِيدِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÌyẹn nítorí ohun tí ọwọ́ yín tì ṣíwájú. Àti pé dájúdájú Allāhu kò níí ṣe àbòsí fún àwọn ẹrú (Rẹ̀).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70