caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Hashr, ẹsẹ 16

Medina · revelation order 101 · 59:16

كَمَثَلِ ٱلشَّيْطَٰنِ إِذْ قَالَ لِلْإِنسَٰنِ ٱكْفُرْ فَلَمَّا كَفَرَ قَالَ إِنِّى بَرِىٓءٌ مِّنكَ إِنِّىٓ أَخَافُ ٱللَّهَ رَبَّ ٱلْعَٰلَمِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀpẹ̀ẹrẹ wọn dà bí aṣ-Ṣaetọ̄n nígbà tí ó bá wí fún ènìyàn pé: “Ṣàì gbàgbọ́.” Nígbà tí ó bá ṣàì gbàgbọ́ (tán), ó máa wí pé: “Dájúdájú èmi yọwọ́ yọsẹ̀ kúrò nínú ọ̀rọ̀ rẹ. Dájúdájú èmi ń páyà Allāhu, Olúwa gbogbo ẹ̀dá.”
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70