caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Jaathiya, ẹsẹ 15

Mecca · revelation order 65 · 45:15

مَنْ عَمِلَ صَٰلِحًا فَلِنَفْسِهِۦ وَمَنْ أَسَآءَ فَعَلَيْهَا ثُمَّ إِلَىٰ رَبِّكُمْ تُرْجَعُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelẸníkẹ́ni tí ó bá ṣe iṣẹ́ rere, fún ẹ̀mí ara rẹ̀ ni. Ẹnikẹ́ni tí ó bá sì ṣe iṣẹ́ aburú, fún ẹ̀mí ara rẹ̀ ni. Lẹ́yìn náà, ọ̀dọ̀ Olúwa yín ni wọn yóò da yín padà sí.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70