caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Muminoon, ẹsẹ 28

Mecca · revelation order 74 · 23:28

فَإِذَا ٱسْتَوَيْتَ أَنتَ وَمَن مَّعَكَ عَلَى ٱلْفُلْكِ فَقُلِ ٱلْحَمْدُ لِلَّهِ ٱلَّذِى نَجَّىٰنَا مِنَ ٱلْقَوْمِ ٱلظَّٰلِمِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNígbà tí o bá jókòó sínú ọkọ̀ ojú-omi náà, ìwọ àti àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ, sọ pé: “Gbogbo ẹyìn ń jẹ́ ti Allāhu, Ẹni tí Ó gbà wá là lọ́wọ́ ijọ alábòsí.”
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70