caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Baqara, ẹsẹ 47

Medina · revelation order 87 · 2:47

يَٰبَنِىٓ إِسْرَٰٓءِيلَ ٱذْكُرُوا۟ نِعْمَتِىَ ٱلَّتِىٓ أَنْعَمْتُ عَلَيْكُمْ وَأَنِّى فَضَّلْتُكُمْ عَلَى ٱلْعَٰلَمِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelẸ̀yin ọmọ ’Isrọ̄’īl, ẹ rántí ìdẹ̀ra Mi, èyí tí Mo fi ṣèdẹ̀ra fún yín àti pé dájúdájú Èmí gbọ́lá fún yín lórí àwọn ẹ̀dá (àsìkò yín).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70