caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Maryam, ẹsẹ 24

Mecca · revelation order 44 · 19:24

فَنَادَىٰهَا مِن تَحْتِهَآ أَلَّا تَحْزَنِى قَدْ جَعَلَ رَبُّكِ تَحْتَكِ سَرِيًّا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNígbà náà, (mọlāika) pè é láti ìsàlẹ̀ ọ̀dọ̀ rẹ̀ pé: "Má ṣe banújẹ́. Dájúdájú Olúwa rẹ ti ṣe odò kékeré kan sí ìsàlẹ̀ ọ̀dọ̀ rẹ.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70