caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ibrahim, ẹsẹ 47

Mecca · revelation order 72 · 14:47

فَلَا تَحْسَبَنَّ ٱللَّهَ مُخْلِفَ وَعْدِهِۦ رُسُلَهُۥٓ إِنَّ ٱللَّهَ عَزِيزٌ ذُو ٱنتِقَامٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, má ṣe lérò pé Allāhu yóò yapa àdéhùn Rẹ̀ tí Ó ṣe fún àwọn Òjíṣẹ́ Rẹ̀. Dájúdájú Allāhu ni Alágbára, Olùgbẹ̀san.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70