caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Hud, ẹsẹ 99

Mecca · revelation order 52 · 11:99

وَأُتْبِعُوا۟ فِى هَٰذِهِۦ لَعْنَةً وَيَوْمَ ٱلْقِيَٰمَةِ بِئْسَ ٱلرِّفْدُ ٱلْمَرْفُودُ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelA fi ègún tẹ̀lé wọn nílé ayé yìí àti ní Ọjọ́ Àjíǹde. Ẹ̀bùn náà tí wọ́n fún wọn ní tẹ̀léǹtẹ̀lé (ègún àti Iná) sì burú.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70